Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 1:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati o fi ọrọ̀ ijọba rẹ̀ ti o logo, ati ọṣọ iyebiye ọlanla rẹ̀ han lọjọ pipọ̀, ani li ọgọsan ọjọ.
Pín
Est 1YBCVEst 1:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ṣe àfihàn púpọ̀ ọrọ̀ ìjọba rẹ̀ àti dídán àti ògo ọláńlá rẹ̀ fún ọgọ́sàn-án ọjọ́ gbáko.
Pín
Est 1BMYOEst 1:4YCE(Yoruba Bible)
Fún odidi ọgọsan-an (180) ọjọ́ ni ọba fi ń fi ògo ìjọba rẹ̀ hàn, pẹlu ọrọ̀ ati dúkìá rẹ̀.
Pín
Est 1YCE