Efe 4:4 - Compare All Versions

Efe 4:4 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ara kan ni mbẹ, ati Ẹmí kan, ani bi a ti pè nyin sinu ireti kan ti ipè nyin

Efe 4:4 YCE (Yoruba Bible)

Ara kan ni ó wà, ati Ẹ̀mí kan, gẹ́gẹ́ bí ìpè tí a ti pè yín ti jẹ́ ti ìrètí kan.

Efe 4:4 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ara kan ni ń bẹ, àti Ẹ̀mí kan, àní bí a ti pè yín sínú ìrètí kan nígbà tí a pè yín.