Efe 2:20 - Compare All Versions
Efe 2:20 YBCV (Bibeli Mimọ)
A si ngbé nyin ró lori ipilẹ awọn aposteli, ati awọn woli, Jesu Kristi tikararẹ̀ jẹ pàtaki okuta igun ile
Pín
Efe 2 YBCVEfe 2:20 YCE (Yoruba Bible)
Lórí àwọn aposteli ati àwọn wolii ni a ti fi ìpìlẹ̀ ìdílé yìí lélẹ̀, Kristi Jesu fúnrarẹ̀ sì ni òkúta igun ilé.
Pín
Efe 2 YCEEfe 2:20 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
a sì ń gbé yín ró lórí ìpìlẹ̀ àwọn aposteli, àti àwọn wòlíì, pẹ̀lú Jesu Kristi fúnra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí pàtàkì òkúta igun ilé.
Pín
Efe 2 BMYO