Efe 1:20 - Compare All Versions
Efe 1:20 YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyiti o ti ṣiṣẹ ninu Kristi, nigbati o ti jí dide kuro ninu okú, ti o si fi i joko li ọwọ́ ọtún ninu awọn ọrun
Pín
Efe 1 YBCVEfe 1:20 YCE (Yoruba Bible)
Ó fi agbára yìí hàn ninu Kristi nígbà tí ó jí i dìde ninu òkú, tí ó mú un jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ lọ́run.
Pín
Efe 1 YCEEfe 1:20 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
èyí tí ó fi sínú Kristi, nígbà tí o ti jí dìde kúrò nínú òkú, tí ó sì mú un jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún nínú àwọn ọ̀run.
Pín
Efe 1 BMYO