Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Oni 4:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitorina mo yìn okú ti o ti kú pẹ jù awọn alãye ti o wà lãye sibẹ.
Pín
Oni 4YBCVOni 4:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo jowú àwọn tí wọ́n ti kú tí wọ́n sì ti lọ, ó sàn fún wọn ju àwọn tí wọ́n sì wà láààyè lọ.
Pín
Oni 4BMYOOni 4:2YCE(Yoruba Bible)
Mo wá rò ó pé, àwọn òkú, tí wọ́n ti kú, ṣe oríire ju àwọn alààyè tí wọ́n ṣì wà láàyè lọ.
Pín
Oni 4YCE