Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Oni 3:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Ìgba bibini, ati ìgba kikú, ìgba gbigbin ati ìgba kika ohun ti a gbin
Oni 3:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìgbà láti bí àti ìgbà kíkú, ìgbà láti gbìn àti ìgbà láti fàtu.
Oni 3:2YCE(Yoruba Bible)
àkókò bíbí wà, àkókò kíkú sì wà; àkókò gbígbìn wà, àkókò kíkórè ohun tí a gbìn sì wà.