Oni 3:13 - Compare All Versions

Oni 3:13 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ati pẹlu ki olukulùku enia ki o ma jẹ ki o si ma mu, ki o si ma jadùn gbogbo lãla rẹ̀, ẹ̀bun Ọlọrun ni.

Oni 3:13 YCE (Yoruba Bible)

ati pé ẹ̀bùn Ọlọrun ni pé kí olukuluku jẹ, kí ó mu, kí ó sì gbádùn lẹ́yìn làálàá rẹ̀.

Oni 3:13 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Wí pé: kí olúkúlùkù le è jẹ, kí wọn sì mu, kí wọn sì rí ìtẹ́lọ́rùn nínú gbogbo iṣẹ́ wọn ẹ̀bùn Ọlọ́run ni èyí jẹ́.