Deu 8:4 - Compare All Versions
Deu 8:4 YBCV (Bibeli Mimọ)
Aṣọ rẹ kò gbó mọ́ ọ lara, bẹ̃li ẹsẹ̀ rẹ kò wú, lati ogoji ọdún yi wá.
Pín
Deu 8 YBCVDeu 8:4 YCE (Yoruba Bible)
Aṣọ kò gbó mọ yín lára, bẹ́ẹ̀ ni ẹsẹ̀ yín kò wú, fún odidi ogoji ọdún yìí.
Pín
Deu 8 YCEDeu 8:4 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Aṣọ yín kò gbó mọ́ ọn yín lọ́rùn bẹ́ẹ̀ ní ẹsẹ̀ yín kò sì wú, ní ogójì ọdún náà.
Pín
Deu 8 BMYO