Deu 8:16 - Compare All Versions
Deu 8:16 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o fi manna bọ́ ọ li aginjù, ti awọn baba rẹ kò mọ̀ rí; ki o le rẹ̀ ọ silẹ, ki o le dan ọ wò, lati ṣe ọ li ore nigbẹhin rẹ
Pín
Deu 8 YBCVDeu 8:16 YCE (Yoruba Bible)
ẹni tí ó fi mana tí àwọn baba yín kò jẹ rí bọ́ yín ninu aṣálẹ̀, kí ó lè tẹ orí yín ba, kí ó sì dán yín wò láti ṣe yín ní rere níkẹyìn.
Pín
Deu 8 YCEDeu 8:16 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fún yín ní manna láti jẹ nínú aginjù, ohun tí àwọn baba yín kò mọ̀ rí, kí Òun bá à le tẹ orí yín ba kí ó sì lè dán an yín wò, kí ó bá à lè dára fún un yín.
Pín
Deu 8 BMYO