Deu 31:9 - Compare All Versions
Deu 31:9 YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si kọwe ofin yi, o si fi i fun awọn alufa awọn ọmọ Lefi, ti ima rù apoti majẹmu OLUWA, ati fun gbogbo awọn àgba Israeli.
Pín
Deu 31 YBCVDeu 31:9 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Mose kọ òfin yìí kalẹ̀ ó sì fi fún àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Lefi, tí ń gbé àpótí ẹ̀rí OLúWA, àti fún gbogbo àwọn àgbàgbà ní Israẹli.
Pín
Deu 31 BMYODeu 31:9 YCE (Yoruba Bible)
Mose bá kọ òfin yìí sílẹ̀, ó fún àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n ru àpótí majẹmu OLUWA ati gbogbo àwọn àgbààgbà Israẹli.
Pín
Deu 31 YCE