Deu 10:18 - Compare All Versions

Deu 10:18 YBCV (Bibeli Mimọ)

On ni ima ṣe idajọ alainibaba ati opó, o si fẹ́ alejò, lati fun u li onjẹ ati aṣọ.

Deu 10:18 YCE (Yoruba Bible)

A máa ṣe ìdájọ́ òtítọ́ fún àwọn aláìníbaba ati àwọn opó. Ó fẹ́ràn àwọn àlejò, a sì máa fún wọn ní oúnjẹ ati aṣọ.

Deu 10:18 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ó máa ń gbẹjọ́ aláìní baba àti opó rò, Ó fẹ́ràn àjèjì, Òun fi aṣọ àti oúnjẹ fún wọn.