Dan 7:2-3
Dan 7:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Danieli dahùn, o si wipe, Mo ri ni iran mi li oru, si kiyesi i, afẹfẹ mẹrẹrin ọrun njà loju okun nla. Ẹranko mẹrin nla si ti inu okun jade soke, nwọn si yatọ si ara wọn.
Pín
Kà Dan 7Danieli dahùn, o si wipe, Mo ri ni iran mi li oru, si kiyesi i, afẹfẹ mẹrẹrin ọrun njà loju okun nla. Ẹranko mẹrin nla si ti inu okun jade soke, nwọn si yatọ si ara wọn.