Kol 1:22
Kol 1:22 Yoruba Bible (YCE)
ni Ọlọrun wá mú wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu ara rẹ̀ nípa ikú ọmọ rẹ̀, kí ó lè sọ yín di ẹni tí ó mọ́, tí kò ní àbùkù, tí kò sì ní ẹ̀sùn níwájú rẹ̀
Pín
Kà Kol 1Kol 1:22 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ninu ara rẹ̀ nipa ikú, lati mu nyin wá iwaju rẹ̀ ni mimọ́ ati ailabawọn ati ainibawi
Pín
Kà Kol 1