Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Amo 3:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹnyin nikan ni mo mọ̀ ninu gbogbo idile aiye: nitorina emi o bẹ̀ nyin wò nitori gbogbo ẹ̀ṣẹ nyin.
Amo 3:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ìwọ nìkan ni ẹni tí mo yàn nínú gbogbo àwọn ìran ayé yìí; nígbà náà èmi ó jẹ ọ́ ní yà fún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.”
Amo 3:2YCE(Yoruba Bible)
“Ẹ̀yin nìkan ni mo mọ̀ láàrin gbogbo aráyé, nítorí náà, n óo jẹ yín níyà nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín.