Iṣe Apo 9:7 - Compare All Versions

Iṣe Apo 9:7 YBCV (Bibeli Mimọ)

Awọn ọkunrin ti nwọn si mba a re àjo duro, kẹ́kẹ pa mọ́ wọn li ẹnu, nwọn gbọ́ ohùn na, ṣugbọn nwọn kò ri ẹnikan.

Iṣe Apo 9:7 YCE (Yoruba Bible)

Àwọn ọkunrin tí ó ń bá a rìn dúró. Wọn kò sọ ohunkohun. Wọ́n ń gbọ́ ohùn eniyan, ṣugbọn wọn kò rí ẹnìkankan.

Iṣe Apo 9:7 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Àwọn ọkùnrin tí wọ́n sì ń bá Saulu lọ àjò dúró, wọn kò sì le sọ ohun kan, wọn gbọ́ ohùn náà ṣùgbọ́n wọn kò rí ẹnìkan.