Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 9:29YBCV(Bibeli Mimọ)

O si nfi igboiya sọ̀rọ li orukọ Jesu Oluwa, o nsọrọ lòdi si awọn ara Hellene, o si njà wọn niyàn: ṣugbọn nwọn npete ati pa a.

Iṣe Apo 9:29BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ó ń sọ̀rọ̀ lòdì sí àwọn ará Helleni, ó sì ń jà wọ́n ní iyàn; ṣùgbọ́n wọn ń pète láti pa a.

Iṣe Apo 9:29YCE(Yoruba Bible)

ó ń bá àwọn Juu tí ó ń sọ èdè Giriki jiyàn. Ṣugbọn wọ́n gbèrò láti pa á.