Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 9:28BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Saulu sì wà pẹ̀lú wọn, ó ń wọlé, ó sì ń jáde ní Jerusalẹmu. Ó sì ń fi ìgboyà wàásù ni orúkọ Olúwa.
Iṣe Apo 9:28YCE(Yoruba Bible)
Ó bá ń bá wọn gbé ní Jerusalẹmu, ó ń wọlé, ó ń jáde, ó ń fi ìgboyà waasu lórúkọ Oluwa
Pín
Iṣe Apo 9YCE