Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 9:14YBCV(Bibeli Mimọ)
O si gbà aṣẹ lati ọdọ awọn olori alufa wá si ihinyi, lati dè gbogbo awọn ti npè orukọ rẹ.
Iṣe Apo 9:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì gba àṣẹ láti ọ̀dọ̀ àwọn olórí àlùfáà wá sí ìhín yìí, láti de gbogbo àwọn ti ń pe orúkọ rẹ.”
Iṣe Apo 9:14YCE(Yoruba Bible)
Wíwá tí ó tún wá síhìn-ín, ó wá pẹlu àṣẹ láti ọ̀dọ̀ àwọn olórí alufaa láti de gbogbo àwọn tí ó ń pe orúkọ rẹ ni.”
Pín
Iṣe Apo 9YCE