Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 9:10YBCV(Bibeli Mimọ)
Ọmọ-ẹhin kan si wà ni Damasku, ti a npè ni Anania; Oluwa si wi fun u li ojuran pe, Anania. O si wipe, Wò o, emi niyi, Oluwa.
Iṣe Apo 9:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọmọ-ẹ̀yìn kan sì wà ní Damasku, tí a ń pè ni Anania! Olúwa sì wí fún un lójúran pé, “Anania!” Ó sì wí pé, “Wò ó, èmi nìyí, Olúwa.”
Iṣe Apo 9:10YCE(Yoruba Bible)
Ọmọ-ẹ̀yìn Jesu kan wà ní Damasku tí ń jẹ́ Anania. Oluwa pè é ní ojú ìran, ó ní, “Anania!” Anania bá dáhùn pé, “Èmi nìyí, Oluwa.”