Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 8:35YBCV(Bibeli Mimọ)
Filippi si yà ẹnu rẹ̀, o si bẹ̀rẹ lati ibi iwe-mimọ́ yi, o si wasu Jesu fun u.
Iṣe Apo 8:35BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Filipi sí ya ẹnu rẹ̀, bẹ̀rẹ̀ láti ibi ìwé mímọ́ yìí, ó sí wàásù ìyìnrere ti Jesu fún un.
Iṣe Apo 8:35YCE(Yoruba Bible)
Filipi bá tẹnu bọ ọ̀rọ̀. Ó bẹ̀rẹ̀ láti ibi àkọsílẹ̀ yìí, ó waasu ìyìn rere Jesu fún un.
Pín
Iṣe Apo 8YCE