Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 8:34YBCV(Bibeli Mimọ)
Iwẹfa si da Filippi lohùn, o ni, Mo bẹ̀ ọ, ti tani woli na sọ ọ̀rọ yi? ti ara rẹ̀, tabi ti ẹlomiran?
Iṣe Apo 8:34BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwẹ̀fà náà sì sọ fún Filipi pé, “Mo bẹ̀ ọ́ sọ fún mi, nípa ta ni wòlíì náà ń sọ ọ̀rọ̀ yìí, nípa ara rẹ̀ tàbí nípa ẹlòmíràn?”
Iṣe Apo 8:34YCE(Yoruba Bible)
Ìwẹ̀fà náà sọ fún Filipi pé, “Mo bẹ̀ ọ́, ọ̀rọ̀ ta ni wolii Ọlọrun yìí ń sọ, ọ̀rọ̀ ara rẹ̀ ni tabi ọ̀rọ̀ ẹlòmíràn?”
Pín
Iṣe Apo 8YCE