Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 8:30YBCV(Bibeli Mimọ)
Filippi si sure lọ, o gbọ́, o nkà iwe woli Isaiah, o si bi i pe, Ohun ti iwọ nkà nì, o yé ọ?
Iṣe Apo 8:30BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Filipi si súré lọ, ó gbọ́ ti ó ń ka ìwé wòlíì Isaiah, Filipi sì bí i pé, “Ohun tí ìwọ ń kà yìí ha yé ọ bí?”
Iṣe Apo 8:30YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí Filipi sáré, tí ó súnmọ́ ọn, ó gbọ́ tí ó ń ka ìwé wolii Aisaya. Ó bi í pé, “Ǹjẹ́ ohun tí ò ń kà yé ọ?”
Pín
Iṣe Apo 8YCE