Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 7:37YBCV(Bibeli Mimọ)
Eyi ni Mose na ti o wi fun awọn ọmọ Israeli pe, Woli kan li Oluwa Ọlọrun nyin yio gbé dide fun nyin ninu awọn arakunrin nyin, bi emi; on ni ki ẹ gbọ́ tirẹ.
Iṣe Apo 7:37BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èyí ni Mose náà ti ó wí fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘Ọlọ́run yóò gbé wòlíì kan bí èmi dìde nínú àwọn ènìyàn yín.’
Iṣe Apo 7:37YCE(Yoruba Bible)
Mose yìí ni ó sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘Ọlọrun yóo gbé wolii kan bí èmi dìde fun yín láàrin àwọn arakunrin yín.’
Pín
Iṣe Apo 7YCE