Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 7:30YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati ogoji ọdún si pé, angẹli Oluwa farahàn a ni ijù, li òke Sinai, ninu ọwọ́ iná ni igbẹ́.
Iṣe Apo 7:30BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà tí ogójì ọdún sì pé, angẹli Olúwa fi ara han Mose ní ijù, ní òkè Sinai, nínú ọ̀wọ́-iná nínú igbó.
Iṣe Apo 7:30YCE(Yoruba Bible)
“Lẹ́yìn ogoji ọdún, angẹli kán yọ sí i ninu ìgbẹ́ tí ń jóná ní aṣálẹ̀ lẹ́bàá òkè Sinai.
Pín
Iṣe Apo 7YCE