Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 7:22YBCV(Bibeli Mimọ)
A si kọ́ Mose ni gbogbo ọgbọ́n ará Egipti, o si pọ̀ li ọ̀rọ ati ni iṣe.
Iṣe Apo 7:22BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A sì kọ́ Mose ni gbogbo ọgbọ́n ara Ejibiti, ó sì pọ̀ ni ọ̀rọ̀ àti ní ìṣe.
Iṣe Apo 7:22YCE(Yoruba Bible)
Gbogbo ọgbọ́n àwọn ará Ijipti ni wọ́n fi kọ́ Mose. Ati ọ̀rọ̀ sísọ, ati iṣẹ́ ṣíṣe kò sí èyí tí kò mọ̀ ọ́n ṣe.
Pín
Iṣe Apo 7YCE