Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 7:20YBCV(Bibeli Mimọ)
Li akokò na li a bí Mose, ẹniti o li ẹwà pipọ, ti nwọn si bọ́ li oṣù mẹta ni ile baba rẹ̀
Iṣe Apo 7:20BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní àkókò náà ni a bí Mose ọmọ tí ó se iyebíye, tí wọn sí bọ́ lóṣù mẹ́ta ni ilé baba rẹ̀.
Iṣe Apo 7:20YCE(Yoruba Bible)
Ní àkókò yìí ni a bí Mose. Ó dára lọ́mọ pupọ. Àwọn òbí rẹ̀ tọ́ ọ fún oṣù mẹta ninu ilé baba rẹ̀
Pín
Iṣe Apo 7YCE