Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 7:17YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bi akokò ileri ti Oluwa ṣe fun Abrahamu ti kù si dẹ̀dẹ, awọn enia na nrú, nwọn si nrẹ̀ ni Egipti
Iṣe Apo 7:17BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà tí àkókò tí Ọlọ́run yóò mú ìlérí tí ó ṣe fún Abrahamu ṣẹ kù sí dẹ̀dẹ̀, àwọn ènìyàn wa ń gbèrú si gidigidi ní iye ní ilẹ̀ Ejibiti.
Iṣe Apo 7:17YCE(Yoruba Bible)
“Nígbà tí ó fẹ́rẹ̀ tó àkókò tí ìlérí tí Ọlọrun ṣe fún Abrahamu yóo ṣẹ, àwọn eniyan náà wá túbọ̀ ń pọ̀ níye ní Ijipti.
Pín
Iṣe Apo 7YCE