Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 7:16YBCV(Bibeli Mimọ)
A si gbe wọn lọ si Sikemu, a si tẹ́ wọn sinu ibojì ti Abrahamu rà ni iye-owo fadaka lọwọ awọn ọmọ Emoru baba Sikemu.
Iṣe Apo 7:16BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A sì gbé òkú wọn padà wá sí Ṣekemu, a sì tẹ́ wọn sínú ibojì ti Abrahamu rà ni ọwọ́ àwọn ọmọ Amori ní Ṣekemu ní iye owó wúrà kan.
Iṣe Apo 7:16YCE(Yoruba Bible)
Wọ́n gbé òkú wọn lọ sí Ṣekemu, wọ́n sin wọ́n sinu ibojì tí Abrahamu fowó rà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hamori ní Ṣekemu.
Pín
Iṣe Apo 7YCE