Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 6:14YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori awa gbọ́ o wipe, Jesu ti Nasareti yi yio fọ́ ibi yi, yio si pa iṣe ti Mose fifun wa dà.
Iṣe Apo 6:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí àwa gbọ́ o wí pé Jesu ti Nasareti yìí yóò fọ́ ibí yìí, yóò sì yí àṣà ti Mose fi fún wa padà.”
Iṣe Apo 6:14YCE(Yoruba Bible)
Nítorí a gbọ́ nígbà tí ó sọ pé Jesu ti Nasarẹti yóo wó ilé yìí, yóo yí àwọn àṣà tí Mose fún wa pada.”
Pín
Iṣe Apo 6YCE