Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 6:13YBCV(Bibeli Mimọ)
Nwọn si mu awọn ẹlẹri eke wá, ti nwọn wipe, ọkunrin yi kò simi lati sọ ọ̀rọ-òdi si ibi mimọ́ yi, ati si ofin
Iṣe Apo 6:13BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sí mú àwọn ẹlẹ́rìí èké wá, tiwọn wí pé, “Ọkùnrin yìí kò sinmi láti sọ ọ̀rọ̀-òdì sí ibi mímọ́ yìí, àti sí òfin.
Iṣe Apo 6:13YCE(Yoruba Bible)
Wọ́n wá àwọn ẹlẹ́rìí èké tí wọ́n sọ pé, “Ọkunrin yìí kò yé sọ̀rọ̀ lòdì sí Tẹmpili mímọ́ yìí ati sí òfin Mose.
Pín
Iṣe Apo 6YCE