Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 5:41YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitorina nwọn si lọ kuro niwaju ajọ igbimọ: nwọn nyọ̀ nitori ti a kà wọn yẹ si ìya ijẹ nitori orukọ rẹ̀.
Iṣe Apo 5:41BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà wọn sì lọ kúrò níwájú àjọ ìgbìmọ̀; wọn ń yọ̀ nítorí tí a kà wọ́n yẹ láti jìyà nítorí orúkọ rẹ̀.
Iṣe Apo 5:41YCE(Yoruba Bible)
Wọ́n jáde kúrò níwájú ìgbìmọ̀, wọ́n ń yọ̀ nítorí a kà wọ́n yẹ kún àwọn tí a fi àbùkù kan nítorí orúkọ Jesu.
Pín
Iṣe Apo 5YCE