Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 5:1YBCV(Bibeli Mimọ)
ṢUGBỌN ọkunrin kan ti a npè ni Anania, pẹlu Safira aya rẹ̀, tà ilẹ iní kan.
Iṣe Apo 5:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ọkùnrin kan ti a ń pè ni Anania, pẹ̀lú Safira aya rẹ̀, ta ilẹ̀ ìní kan.
Iṣe Apo 5:1YCE(Yoruba Bible)
Ọkunrin kan tí ń jẹ́ Anania pẹlu Safira, iyawo rẹ̀, ta ilẹ̀ kan.
Pín
Iṣe Apo 5YCE