Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 4:8YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Peteru kún fun Ẹmí Mimọ́, o si wi fun wọn pe, Ẹnyin olori awọn enia, ati ẹnyin àgbagbà.
Iṣe Apo 4:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Peteru kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin olórí àti ẹ̀yin alàgbà àwọn ènìyàn!
Iṣe Apo 4:8YCE(Yoruba Bible)
Nígbà náà ni Ẹ̀mí Mímọ́ wá fún Peteru ní agbára lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́, ó bá sọ fún wọn pé, “Ẹ̀yin ìjòyè láàrin àwọn eniyan ati ẹyin àgbààgbà
Pín
Iṣe Apo 4YCE