Iṣe Apo 4:31
Iṣe Apo 4:31 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbati nwọn gbadura tan, ibi ti nwọn gbé pejọ si mi titi; gbogbo wọn si kún fun Ẹmí Mimọ́, nwọn si nfi igboiya sọ ọ̀rọ Ọlọrun.
Pín
Kà Iṣe Apo 4Iṣe Apo 4:31 Yoruba Bible (YCE)
Bí wọ́n ti ń gbadura, ibi tí wọ́n péjọ sí mì tìtì, gbogbo wọn bá kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, wọ́n bá ń fi ìgboyà sọ ọ̀rọ̀ Ọlọrun.
Pín
Kà Iṣe Apo 4