Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 4:26YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn ọba aiye dide, ati awọn ijoye kó ara wọn jọ si Oluwa, ati si Kristi rẹ̀
Iṣe Apo 4:26BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọba ayé dìde, àti àwọn ìjòyè kó ara wọn jọ sí Olúwa, àti sí ẹni àmì òróró rẹ̀.’
Iṣe Apo 4:26YCE(Yoruba Bible)
Àwọn ọba ayé kó ara wọn jọ, àwọn ìjòyè fohùn ṣọ̀kan, láti dìtẹ̀ sí Oluwa ati sí Mesaya rẹ̀.’
Pín
Iṣe Apo 4YCE