Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 4:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Inu bi wọn, nitoriti nwọn nkọ́ awọn enia, nwọn si nwasu ajinde kuro ninu okú ninu Jesu.
Iṣe Apo 4:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Inú bí wọn, nítorí tí wọn kọ́ àwọn ènìyàn, wọ́n sì ń wàásù àjíǹde kúrò nínú òkú nínú Jesu.
Iṣe Apo 4:2YCE(Yoruba Bible)
Inú bí wọn nítorí wọ́n ń kọ́ àwọn eniyan pé àwọn òkú yóo jí dìde. Wọ́n fi ajinde ti Jesu ṣe àpẹẹrẹ.
Pín
Iṣe Apo 4YCE