Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 3:11YBCV(Bibeli Mimọ)
Bi arọ ti a mu larada si ti di Peteru on Johanu mu, gbogbo enia jumọ sure jọ tọ̀ wọn lọ ni iloro ti a npè ni ti Solomoni, ẹnu yà wọn gidigidi.
Iṣe Apo 3:11BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí arọ ti a mú láradá sì ti di Peteru àti Johanu mú, gbogbo ènìyàn jùmọ̀ súre tọ̀ wọ́n lọ ni ìloro ti a ń pè ní ti Solomoni, pẹ̀lú ìyàlẹ́nu ńlá.
Iṣe Apo 3:11YCE(Yoruba Bible)
Bí ọkunrin náà ti rọ̀ mọ́ Peteru ati Johanu, gbogbo àwọn eniyan sáré pẹlu ìyanu lọ sọ́dọ̀ wọn ní ọ̀dẹ̀dẹ̀ tí à ń pè ní ti Solomoni.
Pín
Iṣe Apo 3YCE