Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 27:9YBCV(Bibeli Mimọ)

Nigbati a si ti sọ ọjọ pipọ nù, ti a-ti ta igbokun wa idi ewu tan, nitori Awẹ ti kọja tan, Paulu da imọran

Iṣe Apo 27:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nígbà ti a sì ti sọ ọjọ́ púpọ̀ nù, àti pé ìrìnàjò wa sì ti léwu gan an nítorí nísinsin yìí àwẹ̀ ti kọjá lọ, Paulu dá ìmọ̀ràn.

Iṣe Apo 27:9YCE(Yoruba Bible)

A pẹ́ níbẹ̀. Ewu ni bí a bá fẹ́ máa bá ìrìn àjò wa lọ nítorí ọjọ́ ààwẹ̀ ti kọjá. Paulu bá gbà wọ́n níyànjú