Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 26:9YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi tilẹ rò ninu ara mi nitõtọ pe, o yẹ ki emi ki o ṣe ọpọlọpọ ohun òdi si orukọ Jesu ti Nasareti.
Iṣe Apo 26:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi tilẹ̀ rò nínú ará mi nítòótọ́ pé, ó yẹ ki èmi ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun lòdì sí orúkọ Jesu tí Nasareti.
Iṣe Apo 26:9YCE(Yoruba Bible)
“Nígbà kan rí èmi náà rò pé ó jẹ mí lógún láti tako orúkọ Jesu ará Nasarẹti. Kí ni n ò ṣe tán?