Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 26:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Iwà aiye mi lati igba ewe mi, bi o ti ri lati ibẹrẹ, lãrin orilẹ-ede mi ati ni Jerusalemu, ni gbogbo awọn Ju mọ̀.
Iṣe Apo 26:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Àwọn Júù mọ irú ìgbé ayé tí mo ń gbé láti ìgbà èwe mi, láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé mi ní orílẹ̀-èdè mi àti ní Jerusalẹmu.
Iṣe Apo 26:4YCE(Yoruba Bible)
“Gbogbo àwọn Juu ni wọ́n mọ̀ bí mo ti lo ìgbésí ayé mi láti ìbẹ̀rẹ̀ ní ìgbà èwe mi nígbà tí mò ń gbé Jerusalẹmu láàrin àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè wa.