Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 26:19YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitorina, Agrippa ọba, emi kò ṣe aigbọran si iran ọ̀run na.

Iṣe Apo 26:19BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

“Nítorí náà, Agrippa ọba, èmi kò ṣe àìgbọ́ràn sì ìran ọ̀run náà.

Iṣe Apo 26:19YCE(Yoruba Bible)

“Nítorí náà, Agiripa Ọba Aláyélúwà, n kò ṣe àìgbọràn sí ìran tí ó ti ọ̀run wá.