Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 26:12YBCV(Bibeli Mimọ)
Ninu rẹ̀ na bi mo ti nlọ si Damasku ti emi ti ọlá ati aṣẹ ikọ̀ lati ọdọ awọn olori alufa lọ
Iṣe Apo 26:12BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nínú irú ìrìnàjò yìí ní mo ń bá lọ sí Damasku pẹ̀lú ọlá àti àṣẹ ikọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn olórí àlùfáà.
Iṣe Apo 26:12YCE(Yoruba Bible)
“Irú eré báyìí ni mò ń sá tí mò fi ń lọ sí Damasku ní ọjọ́ kan, pẹlu ìwé àṣẹ láti ọ̀dọ̀ àwọn olórí alufaa.