Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 23:8YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitoriti awọn Sadusi wipe, kò si ajinde, tabi angẹli, tabi ẹmí: ṣugbọn awọn Farisi jẹwọ mejeji.
Iṣe Apo 23:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí àwọn Sadusi wí pé, kò sì àjíǹde, tàbí angẹli, tàbí ẹ̀mí: ṣùgbọ́n àwọn Farisi jẹ́wọ́ méjèèjì.
Iṣe Apo 23:8YCE(Yoruba Bible)
Nítorí àwọn Sadusi sọ pé kò sí ajinde, bẹ́ẹ̀ ni kò sí angẹli tabi àwọn ẹ̀mí; ṣugbọn àwọn Farisi gbà pé mẹtẹẹta wà.