Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 23:24YBCV(Bibeli Mimọ)
O si wipe, ki nwọn pèse ẹranko, ki nwọn gbé Paulu gùn u, ki nwọn si le mu u de ọdọ Feliksi bãlẹ li alafia.
Iṣe Apo 23:24BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì wí pé, kí wọn pèsè ẹṣin, kí wọ́n gbé Paulu gùn ún; kí wọ́n sì lè mú un dé ọ̀dọ̀ Feliksi baálẹ̀ ní àlàáfíà.”
Iṣe Apo 23:24YCE(Yoruba Bible)
Ẹ tọ́jú àwọn ẹṣin tí Paulu yóo gùn, kí ẹ sìn ín dé ọ̀dọ̀ Fẹliksi gomina ní alaafia.”