Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 20:34YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹnyin tikaranyin sá mọ̀ pe, ọwọ́ wọnyi li o ṣiṣẹ fun aini mi, ati ti awọn ti o wà pẹlu mi.
Iṣe Apo 20:34BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin tìkára yín sá à mọ̀ pé, ọwọ́ mi wọ̀nyí ni mo fi ṣiṣẹ́ láti fi pèsè fún àìní mi, àti tí àwọn tí ó wà pẹ̀lú mi.
Iṣe Apo 20:34YCE(Yoruba Bible)
Ẹ̀yin fúnra yín mọ̀ pé ọwọ́ ara mi yìí ni mo fi ṣiṣẹ́ tí mo fi ń gbọ́ bùkátà mi ati ti àwọn ẹlẹgbẹ́ mi.