Iṣe Apo 2:8-9
Iṣe Apo 2:8-9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẽha si ti ṣe ti awa fi ngbọ́ olukuluku li ede wa ninu eyiti a bí wa? Awọn ará Partia, ati Media, ati Elamu, ati awọn ti ngbé Mesopotamia, Judea, ati Kappadokia, Pontu, ati Asia
Pín
Kà Iṣe Apo 2