Iṣe Apo 2:5-6
Iṣe Apo 2:5-6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Awọn Ju olufọkànsin lati orilẹ-ede gbogbo labẹ ọrun si ngbe Jerusalemu. Nigbati nwọn si gbọ iró yi, ọ̀pọlọpọ enia pejọ, nwọn si damu, nitoriti olukuluku gbọ́ nwọn nsọ̀rọ li ède rẹ̀.
Pín
Kà Iṣe Apo 2