Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 2:5YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn Ju olufọkànsin lati orilẹ-ede gbogbo labẹ ọrun si ngbe Jerusalemu.
Iṣe Apo 2:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn Júù olùfọkànsìn láti orílẹ̀-èdè gbogbo lábẹ́ ọ̀run sì ń gbé Jerusalẹmu.
Iṣe Apo 2:5YCE(Yoruba Bible)
Ní àkókò náà, àwọn Juu tí wọ́n jẹ́ olùfọkànsìn ti gbogbo orílẹ̀-èdè ayé wá, wọ́n wà ní Jerusalẹmu.
Pín
Iṣe Apo 2YCE