Iṣe Apo 2:43 - Compare All Versions
Iṣe Apo 2:43 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ̀rù si ba gbogbo ọkàn: iṣẹ iyanu ati iṣẹ àmi pipọ li a ti ọwọ́ awọn aposteli ṣe.
Iṣe Apo 2:43 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀rù sí ba gbogbo ọkàn; iṣẹ́ ìyanu àti iṣẹ́ àmì púpọ̀ ni a ti ọwọ́ àwọn aposteli ṣe.
Iṣe Apo 2:43 YCE (Yoruba Bible)
Ẹ̀rù àwọn onigbagbọ wá ń ba gbogbo eniyan. Ọpọlọpọ ni iṣẹ́ ìyanu ati iṣẹ́ abàmì tí a ti ọwọ́ àwọn aposteli ṣe.