Iṣe Apo 2:32 - Compare All Versions
Iṣe Apo 2:32 YBCV (Bibeli Mimọ)
Jesu na yi li Ọlọrun ti ji dide, ẹlẹri eyiti gbogbo wa iṣe.
Iṣe Apo 2:32 YCE (Yoruba Bible)
Jesu yìí ni Ọlọrun jí dìde. Gbogbo àwa yìí sì ni ẹlẹ́rìí.
Iṣe Apo 2:32 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jesu náà yìí ni Ọlọ́run ti jí dìde sí ìyè, àwa pẹ̀lú sì jẹ́rìí sí èyí.